Àkòdì Òrìṣà
Àkòdì Òrìṣà:
a dream is gradually taking shape.
Interested in some of my published works?
Follow Me
Àkòdì Òrìṣà:
a dream is gradually taking shape.
To all Omo a yọ orù bá wọn tọ́jú ọmọ tuntun;
Ọmọ́ gbó,
Orù ò gbó:
the offspring of those who bring out the orù pot of herbs to care for infants;
the baby prospers,
and the pot does not falter.”
YORÙBÁ DÌDE
Ọmọ Yorùbá ẹ dìde
Dìde, dìde, dìde.
Ẹyin Yorùbá ẹ dìde
Dìde, dìde, dìde.
Gbogbo Yorùbá ẹ dìde
Dìde, dìde, dìde.
Ọjọ́ ti pé, ẹ dìde
Dìde, dìde, dìde.
Ẹ má sùn mọ́, ẹ dìde
Dìde, dìde, dìde.
Iṣẹ́ ti yá, ẹ dìde
Dìde, dìde, dìde.
Èrù ò bà wá, ẹ dìde
Dìde, dìde, dìde.
Àyà ò fò wá, ẹ dìde
Artist: Moyo Okediji, Painting in the Round Series: Visitors from Another Space/Time.
acrylic on canvas
Dimension: unequal.
Date: 2007
Moyo Okediji
Title: Dem Belleful
Medium: acrylic on canvas
date: 2021
48×36″
The presidential election in Nigeria is postponed for another week.
Who will win between Buhari and Atiku?
(In all seriousness, all other names are not on the ballot).
The question is not whether Buhari will be reelected into office as the president of Nigeria.
Ifa says Buhari will be reelected, whether you like it or not.
Yours truly at the Ohio State University to give a lecture on Friday.